Back Home Next

 

 

 

Klavarskribo ti gbogbo agbaye


Di Akorin /Aluduru logan

Wa ko lati lu duru (keyboard) ati opolopo ohun ijosin ni church

 Iwe orin wa nigbakibga

Awon orin igbakigba ati atayebaye  -Classical-Hymns.

Klavar Music ti se iwadi ijinle ona ti a fi le mu orin kiko rorun bi eniti a nka iwe irohin

Ohun to je Klavar logun ni lati je ki orin je ona ti a fi le mu ayo wo okan, idile ati

 agbegbe ati lati mu ki orin je ona iwosan fun awon omode, agba, ati awon abirun

ti o soro fun lati ko eko

Klavarskribo  ni iwe idaniloju lati owo ajo ti nmojuto ile iwe orin ti Royal School of Music   

  

You may not repost, republish, reproduce, package
and/or redistribute the content of this page,
in whole or in part, without the written permission of the copyright holder.

 

website security


Copyright©1993-2012  The Klavar Trust: All Rights Reserved.